Nigerian gospel music: Tope Alabi – LOGAN TI ODE Ft. TY Bello X George
Tope Alabi – LOGAN TI ODE ft. TY Bello x George Mp3 Download


Tope AlabiLOGAN TI ODE ft. TY Bello x George Mp3 Download

 


Nigerian gospel music: Tope Alabi – LOGAN TI ODE Ft. TY Bello X George, Tope Alabi goes under an incredible motivation of the Holy Spirit to make a music interpretation titled “Logan Ti Ode” which means The Moment He Steps In. This melody is from the Spontaneous love session with TY Bello which ft George as an Instrumentalist.

Enjoy Below

Tope Alabi – LOGAN TI ODE ft. TY Bello x George Mp3 Download


Watch Video LOGAN TI ODE ft. TY Bello x George Mp4 DownloadTope Alabi ft. TY Bello & George – Logan Ti Ode Lyrics

(Verse)
Emi mo oun oju mi tiri, mo mo oun eti mi ti gbo
Mo oun oju mi tiri, mo mo oun eti mi ti gbo
Logan to gbo iro Ayo re o Olugbala, aye mi le to
Logan to gbo iro Ayo re o Olugbala, aye mi le to

Mo mo oun aye ma ti wi, mo mo oun eyan ma ti so
Won ti pe wa ni agan ri, boya won ti pewa lo’olosi ri
Sugbon, logan ti o de o Olugbala, aye mi le to
Logan ti o de o Olugbala, aye e le to

Aye to ti daru tele tele o, logan ti o de
Oro ti eniyan ti fi s’alufani re, logan ti o de
Oro ti ko dara ta ti so si o, logan ti o de
Oruko ti kin se tire ta ti pe o, logan ti o de
Ani logan ti o de o Olugbala, aye e le to
Logan ti o de o Olugbala, aye e le to
Logan ti Jesu de o Olugbala, l’aye e le to

Ko s’oruko t’aye o le pe ni, wa ma peni l’agan l’ona gbo gbo
Bo ba lowo lowo agan ni, bo ba bi mo o agan ni
Bo ba tegba ko dagba agan lo je, sugbon logan ti o de, sope logan ti o de
Ani logan ti o de, lesekese, logan ti o de
Ahah, logan ti o de o Olugbala, l’aye e le to
Logan ti o de o Olugbala, l’aye e le to

Instantly lo’n je be, bo se n debe, won de yi oruko pada

Logan ti o de, eheheh logan ti o de, eyin ta pe l’agan e ma so wi pe, logan ti o de
Awon ta ti fi oruko aburu pe ni’le won yi, logan ti o de
Ahah, logan ti o de o Olugbala, l’aye mi le to
Logan ti o de o Olugbala, l’aye mi le to
Ani eheh, logan ti o de o Olugbala, l’aye mi le to
Ani, logan ti o de o aseda, l’aye mi le to
Ani, logan ti o de o Olorun o, l’aye mi le to
Irawo owuro omo Marry yo sinu oro mi, l’aye mi le to
Ah, alagbara ni Shiloh loba ran ti mi si rere, l’aye mi le to
Enu mi wa kun fu eri o gbogbo, l’aye mi le to
Aye mi gba iyipada otun o logan to de, , l’aye mi le to
Aye mi ba leto l’ota ba wo Iran mi, l’aye mi le to
Aye mi le to lo ta bawo Iran mi, l’aye mi le to
Ota kaworo, enu won gbe tan lori oju kan, l’aye mi le to
Ahah, logan ti o de o Olugbala, l’aye mi le to

(Outro)
Thank you Lord Jesus for all that you are..
Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*